Shakara Oloje Ni - Fela Anikulapo Kuti
To Ba B'Oni Sakara PadePasan Lo Ma Fi Na E Oje L'O Nje
Ki N'O Se Pe O
Sakara Oleje Ni (Chorus)
Sakara Oleje Ni Sakara Oleje Ni
Sakara Oleje Ni Sakara Oleje Ni
Ma Ka Na E
Ma Kan Na E Pa
Iwo Ke, O Ti Mo Mi Ni
To Ba To Ko Duro De Mi O
Duro De Mi Ki Nbo 'So Mi
Wa Je Baba Nla Ia Iro Ni O Ko Le
Ja, Oje Lo Nyo, Ki N'O Se Pe O
Sakara Oleje Nio
Sakara Oleje Ni (Chorus)
Sakara Oleje Ni Sakara Oleje Ni
Sakara Oleje Ni Sakara Oleje Ni
To Ba F'Owo Kan Mi
Jowo Fi Mi Sile
Tabi Ki Lo Nse E
O M'Egbe Ni, Nijo Wo La Degbe
Wa Nibo Lo Ti Ja Wa
Nibo Lo Ti Ja Wa To Lokun Lorun
Emi Pelu Re Ko
Iro Ni O, O Fe Se O Oje Lo Nyo
Ki N'O Se Pe O Sakara Oloje Ni O
Sakara Oleje Ni (Chorus
Sakara Oleje Ni
Sakara Oleje Ni
0 Comments:
Post a Comment
<< Home